[00:02.49] Intro [00:04.69] Ha... yeaaaa [00:05.95] E ribi 9ice ati KWAM ara ba nbi [00:11.54] If you wanna live long [00:13.81] If you wanna stay strong [00:15.53] If you wanna live long and stay strong [00:18.36] Ile la loro (ile la loro) [00:21.05] Dokita a fun e ni imoran heh [00:24.35] If you wanna live long and stay strong [00:26.20] Ile la loro (ile la loro) [00:29.76] Dokita a fun e ni imoran heh [00:31.80] 1 – 9ice [00:32.89] Ogun ibile afun ni ni iwosan [00:34.66] Oloyun a bi were [00:36.19] Lai sise abe [00:37.37] Ewe nje, ogun nje (Kabiyesi o) [00:39.02] Ma se logun without doctor's prescription [00:44.02] Mo n tenu mo [00:46.27] Mo n tenu mo [00:47.66] Call on doctor's attention [00:49.84] If you need solution [00:52.36] Mo n tenu mo Adigun heh, mo n tenu mo [00:55.01] To whom is given, much is expected [00:58.86] Ile a loro [01:01.88] Ile a loro [01:03.66] If you wanna live long and stay strong [01:06.25] Ile la loro (ile la loro) [01:09.23] Dokita a fun e ni imoran heh [01:11.54] If you wanna live long and stay strong [01:13.50] Ile la loro (ile la loro) [01:16.89] Dokita a fun e ni imoran heh [01:18.94] 2 – KWAM 1 [01:20.30] Iwosan ti de o [01:23.13] Alaboyun e mu ra o [01:25.98] Bo ba se pe eni ba re e [01:29.21] Abi koju ma su [01:31.26] Alaboyun o ni ibi omiran to le lo [01:35.45] Ko ja si hospisitu [01:38.16] Tori pe ile la loro o [01:39.92] Agbo n Se dada fun alaboyun sugbon [01:42.55] Ema se fi iwosan si ile [01:45.63] E o gbodo da ogun lo o [01:48.22] Lai se ase dokita o [01:50.34] If you wanna live long and stay strong [01:53.10] Ile la loro (ile la loro) [01:55.90] Dokita a fun e ni imoran heh [01:57.71] If you wanna live long and stay strong [02:00.42] Ile la loro (ile la loro) [02:04.23] Dokita a fun e ni imoran heh [02:06.69] 3 – 9ice [02:07.68] Imo toto lo le segun arun gbogbo [02:10.77] Efan to gboro [02:12.25] Agbon lowo awon to rero [02:14.31] Ki eku ile gba ko so fun ti oko [02:16.73] Cleanliness is essential [02:18.94] Fertilize your potential [02:20.86] And the sound of times on your initial [02:22.69] Imo toto bori arun mo le [02:24.98] La se ni ka se itoju [02:27.10] Ayika alaboyun [02:29.49] Beri alaboyun, kefo wo wowon o [02:33.96] Eja ka se itoju ayika alaboyun [02:37.14] If you wanna live long and stay strong [02:40.39] Ile la loro (ile la loro) [02:43.40] Dokita a fun e ni imoran heh [02:46.43] If you wanna live long and stay strong [02:47.60] Ile la loro (ile la loro) [02:51.86] Dokita a fun e ni imoran heh [02:54.29] If you wanna live long and stay strong [02:56.37] Ile la loro (ile la loro) [02:58.89] Dokita a fun e ni imoran heh [03:02.14]