[00:00.000] 作词 : Ololade Ahmed [00:01.000] 作曲 : Ololade Ahmed [00:14.581] O ti pọ gan-an [00:16.666] Gan-an, gan-an, gan-an [00:19.423] Ẹ ma fi agilinti wọbọ o, kẹ ma fi were we mi [00:23.263] Ẹni ba lọ lo le mọ a bọ le ṣalaye ni [00:26.690] Awọn ọmọ better ti pọ [00:28.849] Keep your money to ba n bọ [00:30.760] Lokeloke la ma lọ, ẹ ri pe Balenciaga yẹn yatọ [00:34.553] Baby wa uhn uhn, mi o raye k'eeyan fẹran kan jẹun [00:37.978] Oje lo jẹ uhn uhn, ko n ṣe iwọ nikan ẹgbẹẹgbẹrun [00:41.623] Haba! Vanessa ẹ bẹrẹ mu kẹ gboju [00:45.348] Ye, is a mental [00:47.487] O lowo o lọ n loyun [00:49.089] Ah sukerike rike bumbum [00:51.264] Ẹ dẹ maa jo gan-an o di dandan [00:53.271] Super extravagance lọmọ [00:55.028] Emi l'Asake medo t'ọn sọ [00:56.869] Baby you catch my feelings ahn ahn [00:59.112] I'm getting bigger [01:00.539] You dey shack my head like gbana [01:02.648] This your booty are you from Ghana? [01:04.459] Ọmọ olo mi ka ma nawọ ya, ma ṣe jẹ k'ọn mọ [01:08.347] This your booty fit to jawaya, o ga de sanmọ [01:11.990] Ibadi yẹn fẹ ki n ṣe wire into your aza [01:15.851] Ọmọ olo mi ye ma gaza [01:19.127] No pressure, wọn da mọ ọga Ade ẹni lọ lo bọ [01:22.671] Wọ America lọ fun tour [01:24.599] Akata wọn pọ lọpọ [01:26.426] Plenty plenty ọmọge [01:28.403] Wọn fẹ jẹ ki n sa nile [01:30.314] Ori mi lo yọ mi, ọta i ba yọ mi [01:34.025] Ọmọ ọpẹ I dey find my way [01:35.684] Make bad belle no come stop my reign [01:37.761] Bẹbẹ n lọ like a moving train [01:39.305] Fun mi ni big big money no chicken change [01:41.481] Owo n bọ, ọla n bọ, alaafia ati igbadun n bọ [01:45.124] I no wan talk plenty talk my record can back it up [01:50.633] La-do-re-mi-fa-mi-so-la (L'Eko) [01:53.260] Oluwa ni ṣọla [01:55.971] Yarinya [02:00.298] Haba! Vanessa ẹ bẹrẹ mu kẹ gboju [02:04.058] Ye, is a mental [02:06.151] O lowo o lọ n loyun [02:07.730] Ah sukerike rike bumbum [02:10.025] Ẹ dẹ maa jo gan-an o di dandan [02:11.952] Super extravagance lọmọ [02:13.728] Emi l'Asake medo t'ọn sọ [02:15.689] Baby you catch my feelings ahn ahn [02:17.937] I'm getting bigger [02:19.412] You dey shack my head like gbana [02:21.337] This your booty are you from Ghana? [02:23.230] Ọmọ olo mi ka ma nawọ ya, ma ṣe jẹ k'ọn mọ [02:27.089] This your booty fit to jawaya, o ga de sanmọ [02:30.982] Ibadi yẹn fẹ ki n ṣe wire into your aza [02:34.642] Ọmọ olo mi ye ma gaza [05:04.117] Mr Money, Money dance, Mr Money, [05:06.477] Money dance, Mr Money, Money dance [05:09.154] Mr Money, Money dance, Mr Money [05:11.495] Money dance, Mr Money, Money dance [05:14.039] Mr Money, Money dance, Mr Money [05:16.539] Money dance